

Renowned Gospel sensation, John Owonibi, and the highly acclaimed music minister, OBA, in collaboration, ‘Olórúko Repete’.
Olórúko Repete’ is a captivating and energetic ministration that showcases the incredible names of God.
Stream/download.
https://evaloadedent.fanlink.to/OlorukoRepete
OLORUKO REPETE lyrics
Chant:
Adani atunida
Aseni atunise
(Tongues)
Akobi ninu awon oku
Ajinde ati iye
Mo gbeoga mosebare
Oloruko repete
Oloruko repete
nba mo gbogbo oruko re
nba fi yin o
Oloruko repete
Oloruko repete (olorun abrahmu,isaki ati jacobu)
Oloruko repete (ogbontagiri ninu ogun)
nba mo gbogbo oruko re (arogundade)
nba fi yin o
Oloruko repete
Full song:
Oloruko repete
Oloruko repete
nba mo gbogbo oruko re
nba fi yin o
Oloruko repete
Oloruko repete
Oloruko repete
nba mo gbogbo oruko re
nba fi yin o
Oloruko repete
(Nitori)
O’un ti ejé semi
Ife re simi
Anu re simi
Lemi nfi yin o
Oloruko repete
O’un ti ejé semi
Ife re simi
Anu re simi
Lemi nfi yin o
Oloruko repete
Chant 2:
Olupinlese
Ati alashepe
Olugbesan
Bishobu okan wa
Ayeraye ninu ayeraye titi ayeraye
Ida ola nla
Ainibere ailopin
Oba mimo mimo alakeji
Alawo funfun ode o run
Abamure ododo binrinkintin
Ekunrere alaye
Oloruko pupo
Oloruko repete
Oloriki ailekà
Mimo mimo ninu awon Otunba
Oluwa oluwa wa
Oruko re ti niyin to o
Olorun to laye o’un orun
OLORUKO nla
Oloriki Oloriki egba á gbeje
O’un ti ejé semi
Ife re simi
Anu re simi
Lemi nfi yin o
Oloruko repete
O’un ti ejé semi
Ife re simi
Anu re simi
Lemi nfi yin o
Oloruko repete
STOP!!!Want To Promote Your Song?
