DOWNLOAD Music: Solomon Ariyibi – Riru Ogo Titun (A New Wave Of Glory).

Sell your song today!
DOWNLOAD Music: Solomon Ariyibi - Riru Ogo Titun (A New Wave Of Glory).

Dr Solomon
‍‍‍Husband and father,
Singer, creator and writer.
Medical Doctor.
[email protected]

Hhhhhhh

DOWNLOAD Music mp3

Lyrics

Riru Ogo Titun (A new wave of glory)
Chorus
Baba wa
S’aye mi
Riru ogo titun
Jeko wo aye mi wa o
Ireti ogo
Mo gbekele o
Buu jade, laye mi ogo.

Verse
Oluwa lo nile
Aye at’ekun inu re
E gbori yin soke
K’Oba ogo wole wa
(Repeat)
Buu jade,
K’aye mi ko se rere
Buu jade,
Somi d’alayo
(Baba mi) wa bu jade
Kaye mi ko gba otun
Buu jade,
Somi d’alayo
Ireti ogo
Emi gbekele o
Buu jade,
Laaye mi, ogo.
(Chorus)
Instruments( ojo Ibukun yoo sii ro)

Vamp 1..
C: ogo aye mi, waa bu jade
R: same
Ewi (poet)
Olorun kiki ogo,
Oba kiki imole
Ologo didan
A to farati bi oke
Onile ola
Ologo to ju ogo lo
Mo bebe
Riru ogo titun, je ko wo inu aye mi
A new wave of glory
A new wave of power
A new wave of anointing
A new wave of blessing
Ko wo inu aye mi
F’aye mi dara ire, Baba ara
Oba ogo
Edumare nla to nsohun gbogbo lodulodu

C: ogo aye mi, wa bu jade
R: same.

Vamp 2
C: bu jade o, Baba
R: ninu aye mi o
C: bu jade o, Baba
R: ninu ise mi o
C: bu jade o, Baba
R: ninu ile mi o…
C: O wa pemi naa leniyan
R: k’ori mi dori apesin o
C: Baba mi, O si pemi naa leniyan (same response)
C: Oga ogo, pemi naa leniyan (same response)
C: Atobajaye, wa pemi naa leniyan
C: Baba mimo, wa pemi naa leniyan
C: Baba ogo pemi naa leniyan
C: Ogo aye mi, waa bu jade
R: Ogo aye mi, waa bu jade.

Facebook…..Ariyibi Olubodunrin

Instagram…..ariyibisolomon.


STOP!!!
Want To Promote Your Song?

DOWNLOAD Music: Solomon Ariyibi - Riru Ogo Titun (A New Wave Of Glory).
Share via
Copy link